Aṣa
Femi Mo
[Verse 1]
O l'oun o fe mi mo, o l'óun o fe mi mo
Won't say ìkan gan-gan to ṣele
O ṣa l'oun o fe mi mo
Aro ọjọ́ ti a wi yi, aro ojo ti a nso
There was nothing to fear, nothing to get me prepared
Ọsán yen lo pe mi, pe oun o ṣe mo

[Refrain]
Okan mi ti wó lu lè
How could you be so cruel?

[Chorus]
Ṣo da bayi?
Nkan t'o ṣé yi o dun mi
Ten years, ojo kan ṣoṣo, out by the curb
Don't say goodbye
Think of all the sweet memories
Ten years, ojo kan ṣoṣo, out by curb

[Verse 2]
Wọn l'awon o fe wa mo, wọn l'awon o fe wa mo
Won't say ìkan gan-gan to ṣele
Wọn ṣa l'awon o fe wa mo
Ife afe ju, ko ni gba ko lawo
Éni o doloro, o wa fe yo wo
Igba ye lo mo pé oun o ṣe mo
[Refrain]
Okan mi ti wó lu lè
How could you be so cruel?

[Chorus]
Ṣo da bayi?
Nkan t'o ṣé yi o dun mi
Ten years, ojo kan ṣoṣo, out by the curb
Don't say goodbye
Think of all the sweet memories
Ten years, ojo kan ṣoṣo, out by curb
Ṣo da bayi?
Nkan t'o ṣé yi o dun mi
Ten years, ojo kan ṣoṣo, out by the curb
Don't say goodbye
Think of all the sweet memories
Ten years, ojo kan ṣoṣo, out by curb