[Intro]
Durọ mọ mi ọmọ durọ mọ mi tonight
Jẹ ka do something tonight
Something tonight
(Del B on the beat)
[Chorus]
Ọmọ lọmọ yẹn
To n jo disco
O fakọsi, o wọ Fendi mi o wọ Kito
Ọmọ gan-an lọmọ yẹn ah
Mo fẹ jẹṣẹ yẹn ah
O fakọsi, o wọ Fendi mi o wọ Kito
[Verse 1]
Wọn ranju wọn ranju
Nibo lo ti wa, nibo lo ti wa?
Wọn a gbele ma gbọ, wọn a gbele ma gba
Guarantee, guarantee
Beautiful, lo tun ṣana (Mm, mm)
Bad belle enemies, won't let me drink water drop cup, eh
Wọn tun ti n sọrọ mi
Put it inside your tea make you drink am, oh
Captivating, captivating
Mo gbe, bad girl, ọmọ did not come to play
She no come to play
Uhn awọn lo n ṣere
[Chorus]
Ọmọ lọmọ yẹn
To n jo disco
O fakẹsi, o wẹ Fendi mi o wọ Kito
Ọmọ gan-an lọmọ yẹn an
Mo fẹ jẹṣẹ yẹn ah
O fakọsi, o wọ Fendi mi o wọ Kito
[Verse 2]
Guaranteed, guarantee
Ikorodu touchdown, Yankee
Baby, talk to me nicely
Mo kọ pop, kọ fuji
Competi', competi'
Do I look like I am thirty?
Ade ori ọkin
Wọn gbele ma gbọ, wọn a gbele ma gba
(Iyọnu Ọlọrun) Evеry day
(Iyọnu Ọlọrun) Anyway
(Iyọnu Ọlọrun) Dance to my disco
[Chorus]
Ọmọ lọmọ yẹn
To n jo disco (To n jo disco)
O fakẹsi, o wẹ Fendi mi o wọ Kito
Ọmọ gan-an lọmọ yẹn an
Mo fẹ jẹṣẹ yẹn ah
O fakọsi, o wọ Fendi mi o wọ Kito
[Outro]
Boya ka fagbo bi Fеla (Fagbo bi Fela)
Awọn kan fa cigar (Kan fa cigar)
Wọn n jo wọn n bend down (Wọn n bend down)
Ẹla oju kan ẹla (Oju kan ẹla)
Wọn ni mi fagbo bi Fela (Fagbo bi Fela)
Awọn kan fa cigar (Kan fa cigar)
Wọn njo wọn ẹla (Wọn njo wọn ẹla)
Ẹla oju kan ẹla, oh
Areeky, baby, oh
Oluwaloseyi
Fagbo bi Fela (Fagbo bi Fela)
Tun fa cigar (Tun fa cigar)
Yeah, yeah
O ya ka fagbo bi Fela
Awọn kan fa cigar (Awọn kan fa cigar)
Wọn njo wọn ẹla (Wọn njo wọn ẹla)
Ẹla oju kan ẹla (Ẹla oju kan ẹla )
[?]